DIDACTIC: "OSISE PO, ISE KO PO" BY OLUMIDE SOWUNMI
Osise po,
Opo n se ise won, won si tun sun ekun ise.
Won n raago debi wipe won ko ri owo ho ori.
Bee na ni alapa ma se ise po repete,
Won a fi enu e,
Won a fi idi e,
Won ri owo, ji owo ko, owo dola ati poun pelu-pelu kii tan lowo won, lilo bibo iru won kii won lodo awon aseni lowo ago awusa,
Won a maa se owo bi ele da.
Ailonka won ko se ni idi ope,
Won ko nikan je ni idi pepe,
Won tun n mu oguro pelu si odi,ta googo!
Mo mo pe,
Omowe pupo lo wa,
Sugbon ogooro omowe ko ni o mu oke tabi dari apejopo iru won.
Ki lo de?
Onijo po, janti rere.
Se aye feran lati fi igi omo sile,
Ki o fi paku-gan-dindi se oluko ijo?
Aye ti ya ode,o ni ohun gbon!
E je ka ki awon apapo igi inu aginju ti won fi owo ti olu-igbo lati yan igi omo fun gbedu ni gbigbe?
Ee wa ri iran wo bi-
Igi omo ti ndun kola-kola.
Onkowe po,
Awon ayan gege naa po, janti re re.
Sugbon,
Melo ni a fi owo ba iwe laarin onkowe ti ise won rin ile bi ojo osu mesan-an?
Melo ni onkowe to se iwadii opolopo mo imuna-doko won,
to le rin olukawe re de inu kindinrin ohun edo Foro tabi ti orinrin won yoo mu eniyan mole maa ka iru iwe bee lati paali iwaju de eyin paali?
Onkowe po o,
Beeni mo so,
Enu opolopo won si po pelu,
Sugbon melo ninu won lo je onkowe lati oke wa?
Melo nipa afi oriti ati afi okan si lo di akoni onkowe to tayo ni awujo re tabi ni igboro aye?
Akose mose gbogbo
E ko ni sise o.
Ako ye,ate ye ati ati ataye ri ere pelu.
©OLUMIDE SOWUNMI
-Nigeria
Post a Comment